Nibẹ lo ti jẹ ko di mimọ pe ifẹ toun ni si aṣa ati iṣe lo jẹ koun maa ṣe iranlọwọ to ba yẹ lati mu igbelarugẹ oniruuru aṣa ati iṣẹṣe nilẹ Naijiria.
O ni igbagbọ ileeṣẹ naa ni pe idagbasoke orileede ni lati ni ipasẹ ibọwọ fun ipo ohun ajogunba tii ṣe iṣẹṣe ati awọn alaṣẹ ibilẹ kaakiri.
“Agbara Naijiria duro lori ẹlẹyamẹya. Ni ileeṣẹ Adron Homes, a mọ pe aṣa ati iṣẹṣe kii ṣe idiwọ si idagbasoke, bi ko ṣe ipilẹ ti ilọsiwaju ni lati rọ le," Aarẹ Emmanuking sọ bẹẹ.
No comments:
Post a Comment