IKEDE PATAKI - IROYIN AWIKONKO

IROYIN YAJO-YAJO

AJỌ DAWN

AJỌ DAWN

IKEDE PATAKI


Njẹ iwọ n wa ọna lati ba wa ṣiṣẹ gẹgẹ bi akọroyin ni eyikeyi ilu ti ẹ ba wa, tabi o wu ẹ lati jẹ ọkan lara awọn oludamọnran wa, aaye ti ṣi silẹ bayii fun un yin lati darapọ mọ wa.

Bo si jẹ pe ẹ fẹ ẹ fi iroyin awọn iṣẹlẹ to n ṣẹlẹ ladugbo tabi lagbegbe yin to wa leti ni, ilẹkun ṣi silẹ.
 
Ẹ kan si wa lori Email: iroyinawikonko@gmail.com tabi 07012342712, 08064681551

PIN-IN KAAKIRI