Nipa Wa - IROYIN AWIKONKO

IROYIN YAJO-YAJO

AJỌ DAWN

AJỌ DAWN

Nipa Wa

Iroyin Awikonko kii tun se tuntun mo laarin awon iroyin ori ero ayelujara to n royin pelu ede abinibi Yoruba, to si ti de lati duro digbigbi pelu awon to fee figagbaga pelu e.

Gbogbo eka lati n mu iroyin wa bii;
Lagbo amuludun
Esin,
Oniruuru Ayeye,
Oro Oselu
Odaran
Eko
Asa ati Ise
Iforowero
Ere idaraya ati oniruuru eka iroyin.


...A wa kii gba riba o
...fun igbeleke otito ati awijare

PIN-IN KAAKIRI