A fi ki Bọde George fẹgbẹ PDP ipinlẹ Eko silẹ – Salvador - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, August 24, 2018

A fi ki Bọde George fẹgbẹ PDP ipinlẹ Eko silẹ – Salvador

Alaga fgb oelu PDP nipinl Eko, narebu Moshood Salvador, ti ke si alaga fgb oelu naa lapap niluu Abuja lati le Oloye Bde George atawn eeyan mwaa mi-in kuro ninu gb naa bi wn ba fẹẹ j koun iṣẹ gg bi ipo ti wn yan oun si.


O sr yii l’Ọjb, Tsidee, nigba to n bawmgb naa e ipade p, eyi to waye laduugbo Maryland niluu Eko. O s pe kunrin naa to n pe ara  ni olori gb naa lo n da wahala sil ninugb oelu naa, to si n fẹẹ kawn eeyan wa maa gbaṣẹ lnu r, ki wn to e ohunkohun ati pe inu ile  lo ti fẹẹ j ki wn maa e ohun gbogbo to ba t si gb naa.

Bakan naa lo s pe bi ki i ba plp lrun, o ku di ki Bde George ran oun lwn lori iṣẹl to waye ninu ou keje, nibi ti wn ti pa alaga ijba ibil PDP ni Apapa iyẹn Ọgbẹni Adeniyi Abọriṣadekunrin naa ko fi r sab ahn snigba to s gbogbo ipa ti Bde George ti ko lati mu ifasyin ba gb naa lati ibr pp.

Gẹgẹ bi alaye alaga naa, o ni Bọde atawọn eeyan ẹ gbimọ pọ  lati sọ nnkan ti ko ṣẹlẹ nipa wahala to waye ni Eti Ọsa naa lati fi ran oun lẹwọn ṣugbon oun dupẹ lọwọ awọn ọlọpaa atawọn agbofinro pe wọn ṣisẹ wọn gẹgẹ bi iṣẹ, wọn si ri i daju pe oun  ko mọ nnkan kan nipa wahala naa.

O ṣalaye siwaju pe ’Latigba ta a ti ṣe ipade ẹgbẹ oṣelu wa ni Ọrẹgun nibi tawọn ọmọ ẹgbẹ ti pọ to ẹgbẹrun lọna ogoji, la a ti ri i pe ibi ta a ti ṣe gan-an ko le gba wa mọ, koda bi a ba ni ka a ṣe ni ọfiisi wa, ko le gba ero, idi niyii ta a fi pinnu lati maa ṣe ipade naa kaakiri awọn ijọba ibilẹ wa lati fi maa bawọn ọmọ ẹgbẹ sọrọ.

‘A ti ṣe iru ipade bayii ni Ẹpẹ, Ọjọ, Amuwo Ọdọfin, Oṣodi- Isọlọ atawọn ibo mi-in ti wn fi jẹ ijba ibil mtala ti ko si wahala kankan nibẹ, iru ẹ naa la lọọ ṣe ni Eti-Ọsa lọjọ naa. Ka to br lj naa ni alaga PDP ijba ibil ibẹ to jẹ eeyan ti Bọde George ti kk da awn aga ijokoo ru, ti mo ni ki wn fi sil

O tun s ninu r  pe e lo n sare wnu mto ko to di pe wn br rogbodiyan, lyin-o-ryin loun gb pe wn ti pa Aboriade ugbon nigba to ni awn ti Bde George maa hun irọ jọ, wn s pe oun m nipa bi we pa kunrin naa.

plp awn ayaworan ti wn wa nib, bawnlpaa e ni koun yju plu awlri oun, toun de Panti, e ni wn da gbogbo wn satimle. Am oun dup pe awlpaa atawn agbofinro ri okodoro r.

Salvador ni gbogbo erongba Bde Geroge ni pe gbogbo nnkan ti gb naa ba fẹẹ e, wn gbdwa e nile , to fi m ipade awn oloye gbugbn tawn ko gba fun un, o nile oun gan-an ju ile  to n pn le naa l.

Bakan naa lo s pe aimye owo tara oun loun ti na si apo gb naa, nitori ki ilsiwaju le de bagb naa, ko wa y ki Bde George ti ko lnu nibni wọọdu  maa da gbogbo eto awru, o wa ke si awn oloye gb niluu Abuja lati le kunrin naa kuro ninu gb nitori agba bayej ati agbẹyinbẹbọ jẹ ni.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI