IROYIN AWIKONKO

YAJO-YAJO

OṢELU

KORONAFAIRỌỌSI

KỌỌTU

ERE IDARAYA

AWỌN IROYIN AIPẸ

WOO SI I

Thursday, April 22, 2021

Aye o! Wọn ni Baba Ìjẹ̀ṣà, gbajugbaja òṣèré tíátà f'ipa b'ọmọ ọdún mẹrinla lo pọ l'Ekoo

A mọ riri iṣẹ ti ẹ ṣe - SWAN gbe oṣuba kare f'ẹgbẹ elere idaraya Kwara

Àrokò ni iku Derby jẹ f'awọn Ààrẹ ilẹ̀ Áfríkà, púpọ wọn lo ṣi máa ku - Wòlíì Ayọdele

Awọn ọdọ bọ s'aye ni Kwara, obitibiti ilẹ n'ijọba gba fun wọn lati ṣiṣẹ ọgbin

Tuesday, April 20, 2021

Sanwo-Olu tu aṣiri idi ti ko fi gba Amọtẹkun laaye l'Ekoo

O tan! Ile-ẹjọ Tribuna yẹyẹ Jẹgẹdẹ, wọn l'ẹsun to gbe wa ko kun oju oṣuwọn to

Ọwọ ọlọpaa Ghana te ẹlẹwọn mẹsan-an to salọ ni Naijiria

Lẹyin ti Sanwo-Olu da ọlọpaa ti wọn lu l'ọla, awọn ọmọ Naijiria naa tun da obitibiti owo fun un

O pari o! Wọn f'ẹsun jibiti kan Kọla Ọlọgbọdiyan, agbẹnusọ ẹgbẹ oṣelu PDP

Ọpẹ o! Ipinlẹ Kwara jeere obitibiti owo l'oṣu mẹta akọkọ ọdun 2021

Wahala nbọ! Wọn l'awọn oṣiṣẹ kaakiri Naijiria fẹẹ da iṣẹ silẹ nitori El-Rufai

PIN-IN KAAKIRI