AWọN ARAALU KO Fẹ IJọBA BABA Sọ PE Mọ NIPINLẹ EKO - BABATUNDE GBADAMọSI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, August 27, 2018

AWọN ARAALU KO Fẹ IJọBA BABA Sọ PE Mọ NIPINLẹ EKO - BABATUNDE GBADAMọSI


Oludije gomina labẹ ẹgb oelu ADP nipinl Eko, Babatunde lalere Gbadamsi tp m si BOG ti s pe ijba Baba s pe ti wn n lo nipinl Eko ti su awn araalu wọn si ti sun wọn mọ ogiri, idi niyii ti won fi n wa ẹgbẹ oṣelu ti yoo jẹ ọna abayọ nibi ibo to n b ldun 2019 ti yoo le APC danu.

Babatunde Olalere Gbadamosi
O sr yii lakooko to n ba awn oniroyin sr nibi ipade tawn oloye gb ADP nil Yoruba e, eyi to waye niluu Eko. O sọ pe ijba ti wn n lo lati nnkan bi ogun dun syin lo ti su awn eeyan, bo til j pe o tip ti wn ti fẹẹ le wn danu ugbn ojooro ati awn iṣẹ ibi tawn to wa nijba naa n e ko j.

Gbadamsi s pe ldun 2003, ni wn ti kk fẹẹ fi ibo le wn danu nigba ti ajo eleto idibo nigba naa ti kk kede pe Funṣọ William’s lo wle ugbn nigba tilẹ ọj keji yoo fi m, wn ti ojooro pe awn lawn wle pada ẹlẹẹkeji.

O ni iyn tun l, ldun 2007, tawn araalu tun mura sil lati j ki Funṣọ William’s wle, e lawn ni ibi  da mi legbodo, awn eeyan wa s nigba naa pe awn ko mọ ẹni to pa kunrin naa ugbn idahun temi maa n fun wn ni pe awn to jere nipa iku ni ki wn roo si.

O tun alaye pe ipo to y ki ipinl Eko wa k lo wa a, bi a ba ni ka a s nipa eto r aje atawn idagbasoke, ugbn o ni, nigba to j pe awn bi kan ni wn fẹẹ  maa paṣẹ, ki aṣẹ gbogbo ipinl Eko wa lw wn, o ni asiko ti wa to tawn araalu etan lati fi ibo le wn danu. Ko si nnkan to n jẹ babakresi tabi baba sọ pe mọ.

Oludije naa  tun ṣalaye siwaju pe gb ADP ipinl naa ti mura sil fun yiyan awn oludije ti wn yoo dije labẹ ẹgb naa, o ni gbogbo awn mọ ẹgb ni wn yoo e ojue wn lati dibo fni to ba wuu, o ni gb naa ti kja, ni ti yoo maa fowo ra ibo lw awn mọ ẹgb.

O ni bi awn m ipinl Eko ba le fun gb oelu ADP laaye lati jawe olubori ninu ibo gomina to n bọ naa, gbogbo nnkan tawn fẹẹ ṣe lati le j ki ipinlẹ ọhun ba tawn agbaye yooku mu, ko gba wn ju dun kan l, nitori awn ti ko to Eko lagbaye, o nibi ti wọ de bayii.

Ati pe awn ioro ti ko y ko maa dojuk wa bii omi, ina, atune oju popo lawn araalu n dojuk plu bi owo e n wle, bakan naa, lo ni eto ibanisrwa gan-an ko ja geere to, ti ko si y ko ri bẹẹ, o wa beere pe iru ijba wo wa ni a n lo nipinl Eko.

p awn to n akoso ipinl Eko lo s pe o y ki wn wa nibi ti wn ti n tju ugbn ni bayii, o ni opin ti de ba iru awn aaaju bẹẹ nitori wn ti sun awn araalu kan ogiri, ohun ti wn wa ni ijba tuntun ti yoo le e gbogbo nnkan ti wn ba n f, ti ko ni si pe wn fi ara ni araalu.

O wa s plu idaniloju pe ireti i wa fun gb oelu ADP lati gba akoso ipinl Eko, nitori ariwo ayipada rere ti ki i ṣe ti APC lawn araalu pariwo bayii.

PÍN-IN KÁÀKIRI