KÒ Ṣ'ẸNI TO LE RỌ OLUWO L' ỌBA - ÀWỌN ARÁÀLÚ IWO L'AWỌN WA L'ẸYIN OLUWO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Tuesday, February 18, 2020

KÒ Ṣ'ẸNI TO LE RỌ OLUWO L' ỌBA - ÀWỌN ARÁÀLÚ IWO L'AWỌN WA L'ẸYIN OLUWO


L'ọsan onii làwọn aráàlú Ìwó ń'ipínlẹ̀ Ọṣun ṣe iwọde láti fi hàn wí pé àwọn wá lẹ́yìn Ọba AbdulRọṣheed Akanbi, Oluwo tilu Ìwó bíi ike, àti pé kò ṣeni tó lè rọ ọ l'oye.

Ọ̀rọ̀ tí wọn ń sọ ní pe ki lo fà á tí Ọba Ọgbaagba fẹẹ fi ọ̀pá ọwọ rẹ lu Oluwo pá. 

Díẹ̀ re e lára àwọn fọto iwọde náà:
No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI