Titi di asiko ti a pari akojọpọ iroyin yii lawọn eeyan ṣi fi n kan saara si ileeṣẹ Adron Homes and Properties Limited lori akitiyan ti wọn ṣe nibi ayẹyẹ ọdun aṣa ilẹ Ibadan to waye laipẹ yii.
Papa iṣere Lekan Salami to wa ni Adamasingba ni ayẹyẹ ọdun aṣa ilẹ Ibadan ti waye.
Kii ṣe pe ileeṣẹ Adron Homes ṣagbatẹru eto naa nikan, hi ko ṣe pe wọn tin jẹ gaba gẹgẹ bii ileeṣẹ akọkọ nilẹ Naijiria lẹka eto ile gbigbe.
Diẹ ree lara aworan bi eto naa ṣe lọ
No comments:
Post a Comment