Gomina ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan fun igbakeji nipinlẹ Ọṣun, Ademola Adeleke ti gbe iwe ẹri moyege ti ajọ eleto idibo, INEC fa le e lọwọ, gẹgẹ bi ẹni to jawe olubori ninu eto idibo gomina lọ ba Aarẹ Bọla Tinubu.
Ile agbara ilẹ Naijiria, Aso Rock ni Adeleke ti lọ gbe iwe ẹri naa fun Aarẹ Tinubu




No comments:
Post a Comment