WON NI ATIKU KO FI EGBE OSELU PDP SILE O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, August 27, 2018

WON NI ATIKU KO FI EGBE OSELU PDP SILE O

Ileeṣẹ to n ri si ipolongo Atiku Abubakar fun ti ipo aar labẹ ẹgb oelu PDP ti s pe ko si oot ninu ahesọ ọr kan tawn kan n gbe e jade pe kunrin naa ti n mura lati fgb oelu naa sil lọọ darap mọ ẹgb mi-in, wn ni ir to jinna soot ni.

Ninu atjade kan ti gbni Ṣẹgun owumi, to j agbnus olupolongo fun ileeṣẹ naa gbe jade lj Aiku Sannde, ana an, lo ti s pe awn to n gbe igbekugbe naa jade ko niṣẹ ati pe nnkan ti wn ko ri i ni wọn n sọ lati yi kan awn alatilyin kunrin naa pada ni wn n e e, eyi to s pe wn ti i mu ofo j keji ja.

O ni fawn alaigbagb, ko sigba kankan ti Atiku pinnu lati fgb naa sil bẹẹ si ni sẹ ẹ ko y lati dije fun ipo aar to n b ldun 2019. O ni lati nnkan bii ou meji syin, lo ni kunrin naa ti n rin irinajo kaakiri orilẹ-ede yii lati fi ipinnu han.

O ni titi di akoko yii lawn alatilyin ẹ ṣi n fi if wn han si i pe ko maa nio o, awn wa lyin nibi ibo pamari ti yoo kk waye. Ileeṣẹ olupolongo naa wa ke si awn mọ ẹgb oelu PDP pe ki wn fkanbal ki wn maa jẹ kawn oniskusba ero kan wn je. Idaniloju si wa pe ldun to n b Atiku ni yoo di aar orileede yii.

PÍN-IN KÁÀKIRI