NITORI OWU JIJE! IYAWO ILE FI BILEEDI DA PATANI SI ARA OMO IYALE RẸ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, July 14, 2020

NITORI OWU JIJE! IYAWO ILE FI BILEEDI DA PATANI SI ARA OMO IYALE RẸ

Ko si abiyamọ gidi to ri fọto ọmọ ọdun mẹtala kan ti iyawo baba rẹ fi bileedi da pataani si ara rẹ yamayama ti inu rẹ yoo dun, to si jẹ pe epe buruku l'awọn to ri bi ara ọmọ naa ṣe ri n gbe obinrin naa ṣẹ.

Agbegbe kan ni Ngwo, ipinlẹ Enugu n'iṣẹlẹ naa ti waye laipẹ yii, nigba ti wọn l'awọn araadugbo lọ fi ẹjọ sun awọn ọlọpaa 9th Mile to wa ni Ngwo.

 
Wọn lo o ti pẹ ti obinrin naa ti maa n fi iya jẹ ọmọ ti wọn l'ọmọ ọdun mẹtala ni yii, ṣugbọn eyi to ṣe gbẹyin ni ko dun mọ awọn eeyan ninu rara, to si mu ki wọn lọ fa a le awọn ọlọpaa lọwọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI