Afara Tunde Idiagbon pari fun irọrun araalu Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, February 10, 2024

Afara Tunde Idiagbon pari fun irọrun araalu Kwara


Ṣẹnkẹn bayii ni inu awọn olugbe ilu Ilọrin, ipinlẹ Kwara n dun lori bi ijọba ipinlẹ naa ṣe pari akanṣe afara Ọgagun Tunde Idiagbon to wa lagbegbe Tanke niluu Ilọrin.

Afara yii la gbọ pe yoo adinku ba sunkẹrẹ fakẹrẹ ku lopopona Tanke.

Ipele to wa yii ti de ibi ipari, ti yoo si tun mu ilọsiwaju ba eto ọrọ aje.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI