Eyi lawon oba to leto si ade nile Yoruba - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, May 18, 2017

Eyi lawon oba to leto si ade nile Yoruba

Odun 1931 ni won ti koko gbe atejade oruko awon oba to leto si ade jade, sugbon lojo kefa osu kerin odun 1987 ni won tun tun awon oruko naa gbe jade sinu iwe iroyin Nigerian Tribune.
 
Awon oruko merinlelaadota naa niwonyi;
1. Ooni tile Ife
2. Olowu - Abeokuta
3. Alaafin - Oyo
4. Oba Ado - Ado-Bini
5. Ore Otun - Ottun
6. Orangun - Ila
7. Awujale - Ode (Ijebu Ode)
8. Apero - Ijero
9. Olojudo - Ido Ogundaru
10. Ilara - Ara
11. Elekole - Ikole
12. Owa - Ijesa
13. Oloye - Oye
14. Alake - Abeokuta
15. Ewi - Ado
16. Alaye - Efon
17. Ologotun
18. Akarigbo - Shagamu
19. Oloyi Ife - Oyi Ife (Jebba)
20. Agura - Abeokuta
21. Ogoga - Ikere
22. Oshemowe - Ondo
23. Oshile - Abeokuta
24. Elemure - Emure
25. Onigbajo - Igbajo
26. Olowo Oko - Owo
27. Olowo Ile - Owo
28. Ewusi - Shagamu (Onimakun)
29. Onise - Ise
30. Olojudo - Ido Efon
31. Owa Idanre
32. Alajogun - Ajase
33. Oba Dada - Dahomey
34. Onibara - Abeokuta
35. Onire - Ire ti Oye
36. Oloton - Oton Koro
37. Owa Igbara - Igbara
38. Olojudo - Ido Oshun
39. Oniseri - Iseri
40. Oloja Oke - Imesi I
41. Oloja Oke - Imesi II
42. Ologere - Ogere
43. Olo... - Obagun
44. Elepe - Shagamu (Alupon)
45. Owalubo - Ubo
46. Onilawe - Ilawe
47. Onipokia - Ipokia
48. Onitede - Tede
49. Olohan - Ohan (Ara)

50. Alapa - Agbonda
51. Oloba - Akure
52. Oniro - Iro
53. Olota - Otta
54. Onitori - Itori

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI