Ikunlẹ abiyamọ o! Peju Ogunmola padanu omokunrin kan ṣoṣo to bi - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, September 2, 2025

Ikunlẹ abiyamọ o! Peju Ogunmola padanu omokunrin kan ṣoṣo to bi


Iroyin ibanujẹ nla lo tun sọ lagboole tiata ilẹ Naijiria, lori bi agba oṣerebinrin nni, Peju Ogunmola Omobolanle ṣe padanu ọmọ rẹ kan ṣoṣo to bi.

Ọmọ naa lo padanu ẹmi rẹ sinu ijamba ọkọ lonii, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, oko ere ni wọn ni obinrin naa wa, ti wọn fi firoyin ibanujẹ naa to leti.

Ki Ọlọrun rọ mama naa lọkan, ko si tuu ninu.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI