AYẸYẸ ỌJỌ IBI: EYI NI BI AMUGBALẸGBẸ ṢE GBE OṢUBA KARE FUN IGBAKEJI GOMINA IPINLẸ OGUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, January 8, 2020

AYẸYẸ ỌJỌ IBI: EYI NI BI AMUGBALẸGBẸ ṢE GBE OṢUBA KARE FUN IGBAKEJI GOMINA IPINLẸ OGUN


Ki i ṣe iroyin tuntun mọ pe oni ni ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mẹrinlẹlaadọta (54) ti igbakeji Gomina ipinlẹ Ogun, Onimọ-ẹrọ Nọimọt Salakọ-Oyedele pe l'oke eepẹ, t'awọn eeyan kaakiri agbaye si n ki obinrin naa ku oriire, nitori pe iru awọn anfaani bẹẹ ko wọpọ rara.

Amugbalẹgbẹ igbakeji Gomina ipinlẹ Ogun lori ọrọ iroyin, Arabinrin Oluwaṣeun Boye ninu ọrọ to fi ki Nọimọt Salakọ-Oyedele fun ayẹyẹ ọjọ ibi naa laarọ onii, lo ti ṣapejuwe obinrin naa gẹgẹ bi ẹni to ni itẹriba, to si ko gbogbo awọn ọmọṣẹ ẹ mọra, ko da, ti ni ko fi ẹlẹyamẹya ba ẹnikẹni lo pọ.

Diẹ re e lara awọn nnkan ti Ṣeun Boye sọ nipa ọga rẹ:

Gbajugbaja onkọwe ọmọ orilẹ-ede Scotland kan, to tun jẹ sọrọsọrọ ori redio ati tẹlifiṣan,  William Barclay sọ pe "Oriṣi ọjọ nla meji lo wa l'aye, ọjọ ti a bi ni ati ọjọ ti a ri i pe kinni idi."

Ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mẹrinlelaadọta (54) ti igbakeji Gomina ipinlẹ Ogun, Onimọ-ẹrọ Nọimọt Salakọ-Oyedele lonii, jẹ eyi ti a n fi dupẹ gidigidi lọwọ Allah fun otitọ rẹ to duro digbi lori aye wa.

Obinrin alara, ti igbe aye ẹ kun iṣerere, Salakọ-Oyedele, to jẹ ọmọ bibi ilu Awori, Ota, n'ijọba ibilẹ Ado-Odo/Ota ni wọn bi sinu idile Oloogbe, Ọjọgbọn Lateef ati Arabinrin Rahmat Adebisi Salako l'ọjọ k'ẹjọ, oṣu kinni ọdun 1966.
She is a multi-talented professional with over three decades of proven track records of experience in Consulting, Contracting and Real Estate Sectors.

A highly cerebral goal-getter with a wide range of experience in developing and implementing effective strategies in project management, Engr. Salako-0yedele was a former Managing Director/Chief Executive Officer  between 2014 and 2015 at Glenwood Property Development Company Limited where she served as General Manager Business Development.


Musulumi to tun je olufokansin ni igbakeji Gomina, ẹni tó ti g a orisirisi aami ẹyẹ láwùjọ ni pẹ̀lú, tó sì tún jẹ́ ọ̀kan gbòógì lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Lions Club lorilẹ-ede Nàìjíríà.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI