Ọlaide
Ọṣinuga, Eko - Aarẹ Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba, Iba Gani Adams ti gbe orukọ awọn Oloye rẹ tuntun ti yoo ma a ba ṣiṣẹ bayii sita, ti yoo si ṣayẹyẹ iwuye nla fun gbogbo wọn n'iluu Ekoo l'ọsẹ to n bọ.
Bo tilẹ jẹ pe a ko tii le fidi ẹ mulẹ boya awọn mi-in tun ṣi wa nilẹ ti Aarẹ Ọna Kakanfo fẹẹ fi oye da l'ọla, ṣugbọn diẹ re e ninu orukọ to tẹ AWIKONKO lọwọ laipẹ yii.
Awọn naa ni:
Ọnọrebu Adegboyega A. Salvador
- Ọtun Aarẹ Ọna Kakanfo
Ọgbẹni Ṣẹgun Sanni - Baṣọrun
Aarẹ Ọna Kakanfo
Dọkitọ Gboyega Adejumọ - Gbonka Aarẹ Ọna Kakanfo
Ọgbẹni Amọo Adebọwale - Akinrọgun Aarẹ Ọna Kakanfo
Ọgbẹni Akinọla Ọṣuntokun -
Ajagun-Nla Aarẹ Ọna Kakanfo
Amofin Babajide Tanimọwọ -
Atoloye Aarẹ Ọna Kakanfo
Arabinrin Bọlanle Kuku - Erelu Aarẹ Ọna Kakanfo
Ọgbẹni Abiọdun Adewale Kuku - Ọtun-Balogun Aarẹ Ọna Kakanfo
Oloye Victor Adewale -
Akingbayi Aarẹ Ọna Kakanfo
Alaaji Gani Wahab - Tunaarese Aarẹ Ọna Kakanfo
Alaaji Fatai Adeṣhina - Opo-Akin Aarẹ Ọna Kakanfo
Arabinrin Fatai Adeṣhina - Yeye
Opo-Akin Aarẹ Ọna Kakanfo
Ọtunba Ọbafẹmi Arowoṣhọla -
Agba-Oye Aarẹ Ọna Kakanfo
Arabinrin Esther Oyebọla - Yeye Ọpẹluwa Aarẹ Ọna Kakanfo
Alaaji Hassan Babatunde - Bada Aarẹ Ọna Kakanfo
Ọgbẹni Ibrahim Adeleke - Ọtun
Baaregunwa Aarẹ Ọna Kakanfo
Ọnọrebu Mutiu Kunle Okunọla -
Jagun Aarẹ Ọna Kakanfo
No comments:
Post a Comment