ANTHONY JOSHUA WỌ ÌLÚ ṢÀGÁMÙ, GBOGBO ÌLÚ LÓ MÌ TÌTÌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, February 20, 2020

ANTHONY JOSHUA WỌ ÌLÚ ṢÀGÁMÙ, GBOGBO ÌLÚ LÓ MÌ TÌTÌ


L'ana-an ni gbajúmọ̀ abẹṣẹ-ku-bi-ojo àgbáyé nnì, tó tún jẹ́ ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà, Anthony Joshua balẹ̀ sì ìlú Ṣagamu tíì ṣe olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ogun.


Gbogbo èèyàn jákèjádò ni wọn rọgba yìí ká, pàápàá n'igba tó ń lọ káàkiri láti ṣe abẹwo s'awọn agbègbè kọọkan.


Lara àwọn ibi tó lọ ní Ààfin Akarigbo ilẹ̀ Rẹmọ, tó ti lọọ kí Kabiyesi.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI