O MA ṢE O: Ẹ WO BI WỌN ṢE GUN ỌMỌDUN MẸJỌ L'ABUJA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Monday, February 17, 2020

O MA ṢE O: Ẹ WO BI WỌN ṢE GUN ỌMỌDUN MẸJỌ L'ABUJA

Ọmọdun mẹjọ ti ẹ n wo yii la gbọ pe ọkan lara awọn ti wọn jọ n gbe inu ile kan naa gun l'ọbẹ lati oju oorun to wa.

 
Adugbo Prayer Road, Jikwoyi n'ilu Abuja la gbọ pe iṣẹlẹ naa ti waye laipẹ yii. Iya ọlọmọ meji la gbọ pe o gun ọmọdun mẹjọ ti a f'orukọ bo l'aṣiri yii.

 
Kayeefi n'i'ṣẹlẹ naa ṣi n jẹ tori pe a ko ti i lẹ f'idi ohun to ṣẹlẹ mulẹ l'asiko ti a fi pari iroyin yii.

 
B'iṣẹlẹ naa ṣe waye lo jẹ k'awọn araadugbo wọ iyaale ile to huwa buruku naa lọ teṣan ọlọpaa ti ẹkun Jikwoyi n'ilu Abuja.

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI