NǸKAN DE! ÀWỌN ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ SỌ CORONAVIRUS DI OHUN ÀMÚṢERÉ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Sunday, March 1, 2020

NǸKAN DE! ÀWỌN ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ SỌ CORONAVIRUS DI OHUN ÀMÚṢERÉ


Ọrọ burúkú tòun tẹrin pẹlu báwọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà káàkiri ṣe sọ aarun aṣekupani tó ń tàn káàkiri àgbáyé lásìkò yìí, ìyẹn Coronavirus di ohun tí wọn fi ń ṣe awada láàárín ara wọn.

Kìí ṣe ahesọ wí pé aarun náà tí wọ Nàìjíríà, tó sì jẹ pe o ti ko ẹ̀rù sáwọn èèyàn lọ́kàn gidigidi.

Àwọn fọto imura arambara kan lo tí jáde sórí ayélujára báyìí níbi táwọn ọmọ orilẹ-èdè yìí tí ń arrun Coronavirus ṣe awada.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI