O GA O! ÀWỌN AṢÒFIN ÌPÍNLẸ̀ Ọ̀YỌ́ WỌ AṢỌ ÀMỌ̀TẸ́KÙN LỌ SÍLÉ ÌGBÌMỌ̀ AṢÒFIN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Tuesday, March 3, 2020

O GA O! ÀWỌN AṢÒFIN ÌPÍNLẸ̀ Ọ̀YỌ́ WỌ AṢỌ ÀMỌ̀TẸ́KÙN LỌ SÍLÉ ÌGBÌMỌ̀ AṢÒFIN


Ọrọ náà kọjá awada pátápátá lónìí, nígbà tí gbogbo àwọn aṣofin nipinlẹ Ọ̀yọ́ wọ aṣọ aláwọ̀ àmọ̀tẹ́kùn lọ sí ilé igbimọ aṣofin láti bù ọwọ lu eto ààbò ilẹ̀ Yorùbá.
No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI