FỌTO! ÈYÍ NI ẸKUNRẸRẸ BI WỌN ṢE SÌNKÚ SẸNETỌ AJIMỌBI N'IBADAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, June 28, 2020

FỌTO! ÈYÍ NI ẸKUNRẸRẸ BI WỌN ṢE SÌNKÚ SẸNETỌ AJIMỌBI N'IBADAN


Tiro yẹ lójú òpó, erin ṣubú kò lè dide

Lónìí ní Gómìnà àná nipinlẹ Ọ̀yọ́, Sẹnetọ Abiọla Ajimọbi fi ilẹ̀ ṣe aṣọbora ninu ile ẹ tó wà ní ojúlé kẹfà, àdúgbò Yemọja, Oluyọle, ìlú Ìbàdàn. 

Ṣe làwọn èèyàn ń gbé ara wọn ṣanlẹ gidigidi, tí wọn ń wá ẹkún mu nígbà tí wọn gbé òkú Ajimọbi wọ agbègbè naa. 

Aago mẹ́wàá àárọ̀ òní, 10:05am ni wọn gbé òkú Ajimọbi sínú kòtò. 

Pẹ̀lú ìdí gágá àwọn òṣìṣẹ́ alaabo ni wọn fi sìnkú olóògbé náà, ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà COVID-19.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI