CAMA: KO SẸNI TO TO BẸẸ LATI DA SI ỌRỌ ṢỌỌṢI MI - APOSTLE SULEIMAN GBENA WOJU IJỌBA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, August 29, 2020

CAMA: KO SẸNI TO TO BẸẸ LATI DA SI ỌRỌ ṢỌỌṢI MI - APOSTLE SULEIMAN GBENA WOJU IJỌBA

 
Alaṣe ati oludasilẹ ṣọọṣi Omega Fire Ministries, Apostle Johnson Suleiman ti sọ pe ko sẹni to to bẹẹ lati da si ọrọ idasilẹ ṣọọṣi oun, nitori pe.

Apostle Suleiman sọrọ yii lati tako ofin tuntun tíjọba apapọ ṣẹṣẹ bu ọwọ lu lọjọ keje oṣu yii lori idasilẹ ileeṣẹ aladani, iyẹn Company and Allied Matters Acts (CAMA) lati fi ṣakoso ṣọọṣi.
 
Nigba to n sọrọ, Suleiman ni ko si nnkan to kan ijọba apapọ lori awọn igbimọ idasilẹ ṣọọṣi oun.
 
Yatọ si Suleiman, awọn bi i Biṣọọbu David Oyedepo, Pasitọ Chris Ọyakhilomẹ at'awọn mi in lo tako igbesẹ ijọba tuntun yii.
 
Suleiman sọ pe iranṣẹ eṣu níjọba fẹẹ jẹ lati da si ọrọ idasilẹ ṣọọṣi, to si ni ko lee fẹsẹ mulẹ lailai.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI