Eemọ! Nitori iyawo ẹ kọ ọ silẹ, Baba Ibeji gbe majele jẹ l'Abẹokuta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, April 29, 2021

Eemọ! Nitori iyawo ẹ kọ ọ silẹ, Baba Ibeji gbe majele jẹ l'Abẹokuta


Iru kileyii lo t’ẹnu awọn eeyan jade l’ọsẹ to kọja yii, to si jẹ pe t
iti di asiko ta a pari iroyin yii l’awn eeyan si n beere l’w ara wn lati m idi ti baale ile ni dun mejilelgbn kan, Akinla Imlay Abaymi e gbe majele jẹ, ti ko ti i s’ni to le dahun r. 
 
Ni nnkan bi aago mj kja iṣẹju di al jb ti i e Tsidee ọsẹ to kja yii n’iṣẹl naa waye l’agbegbe Ago-Oko to wa n’itosi apn n’ilu Abokuta.
 
Iyalnu nla gba a ni wn n’iku Abaymi i wọn lo o yan iṣẹ awọn to n tẹ iwe (Printing Press) laayo l’agbegbe Oke-Itoku, Abẹokuta ṣi n j n’igba ti wn ’akiyesi pe oogun apfn ati oogun ekute lo gbe j to fi dagbere f’aye l’j naa. 
 
Gg bi iroyin to t AWIKONKO l’w e s, wn ni inu ou to kja yii, iyn ou kta ni Abaymi ati iyawo ja, ti wn si ni obinrin naa ko di l’ara awn ru lati kuro nile fun Abaymi. 
 
A gb pe e ni Abaymi lu iyawo gidi gan-an, to j pe awn ara adugbo ni wn pada gba obinrin naa sil, ko to o di pe o k’ru r l. 
 
Ko p l’yin ija yii la gb pe Abaymi pada l b iyawo ko le pada sile, to si eleri fun un wi pe oun ko ni i luu m, ugbn ti wn ni obinrin naa loun ko le pada sile naa. 
 
AWIKONKO gb pe ko si nnkan meji to n fa ija l’aaarin Abaymi ati iyawo bi ko ju ti iya arugbo kan ti wn l’oun lo ku gg bi iya onile wọn, nitori ti wn l’ni to n’ile naa ti ku tip, iya arugbo naa la gb pe o maa n ba gbogbo awn araale ja n’igba gbogbo. 
 

j karundinlogbon ou kejila dun to kja la gb pe mama arugbo yii ti br wahala plu awn ara ile, paapaa iyawo Abaymi, ti wn ni e ni mama arugbo naa maa n ’epe raband-raband f’awn to ba n b’inu si. 
 
Gbogbo akitiyan ti wn ni Abaymi e lati le j k’iyawo pada sile la gb pe o ja si pabo, ti wn si ni ironu yii plu awon nnkan to je ko gbe majele j. 
 
Iwadii fi ye wa pe l’aaar j ti Abaymi t’ọpọ awọn eeyan tun n pe ni Baba Ibeji maa gbe majele j, wn ni e lo n ere bi ẹni to ti mọ pe ọjọ naa loun maa ku ni, ti ko si fu nikni lara wi pe oun ni dun kan tabi pe oun n palẹmọ iku oun. 
 
Ọmọbinrin kan ti wọn l’oun pẹlu Baba Ibeji jọ n ṣiṣẹ ni ṣọọbu ni wọn lo o sọ fun pe ko maa gb’adura f’oun bi ẹmi ba ṣe dari ẹ, ti wọn si ni awada ni wọn n fi ọrọ naa ṣe. 
 
Irọlẹ ọjọ naa la gbọ pe Abayọmi sọ pe oun ko mọ bi ara ṣe n ṣe oun, t'awọn eeyan si ni ko maa lọ sile lati lọ tọju ara ẹ. 
 
Asiko ti wọn lo n lọ s’ile la gbọ pe Abayọmi lọ ọ ra oogun apẹfọn ti wọn n pe ni Sniper pẹlu oogun ekute ti wọn n pe ni Push Out, to fi mo oogun kan naa to wa ninu igo. 
 
Wọn ni bo ṣe de’le ni nnkan bi aago meje ọjọ naa lo ki awọn to ba n'iwaju ita, ko to wọ’le lọ ni tiẹ. Ko pẹ la gbọ pe o bẹrẹ si i po awọn oogun naa papọ, ko to da a jẹ, iyẹn ni nnkan bi aago mẹjọ si mẹjọ aabọ. 
 
Lẹyin bi iṣẹju mẹẹdogun ni wọn lo bẹrẹ si i pariwo inu rirun, eyi to mu k'awọn araale sare yọju si i lati mọ nnkan to n ṣẹlẹ. Nibi ti wọn ni wọn ti n beere ọrọ l’ọwọ ẹ lati mọ nnkan to n ṣe e lo ti bẹrẹ si i pọ foomu l'ẹnu. 
 
Eyi ni wọn lo jẹ k'awọn araale sare pe aburo ẹ lati fi to o leti, ti wọn si tun pe iyawo ẹ lori foonu lati fi to oun leti. Ibi ti wọn ti n gbiyanju lati mọ nnkan to ṣẹlẹ ni wọn ti sakiyesi pe awọn oogun ekute ati oogun apẹfọn to da jẹ lo ṣe’ku pa a. 
 
Baba agbalagba to gba Abayọmi s’ile ninu ọrọ to b’AWIKONKO sọ lo ti sọ pe ṣe ni wọn sare wa pe oun nibi t’oun wa wi pe ọkan lara awọn ayalegbe oun ti gbe majele jẹ, to si l’oju ẹsẹ l’oun ti wa lati mọ nnkan to n ṣẹlẹ. 
 
Ninu ọrọ rẹ, o ni “Eeyan jẹjẹ ti mi o ri ko ba ẹnikẹni fa wahala ni Abayọmi. Ko ti i ju ọdun meji to de inu ile yii. Wọn ni iyawo ẹ to lọ lo jẹ ko pa ara rẹ, ṣugbọn mi o le dahun si i, tori pe mi o si nibẹ.”
 
 
Ọkan l'ara awọn araale naa to ba AWIKONKO sọrọ jẹ ko ye wa pe awọn jọ maa n dapara ninu ile ni, to si ni ẹyin ferese l'awọn jọ maa n jokoo si l'alẹ lati gb’atẹgun. 
 
N'igba to n b'AWIKONKO s’ọrọ l’aaarọ ọjọ keji iṣẹlẹ yii, iyawo Abayọmi t’awọn eeyan  pe ni iya ibeji sọ pe ọjọ karun-un oṣu to kọja l’awọn ja, to fi di pe Abayọmi lu oun, to si ni idi niyen toun fi k'ẹru jade. 
 
"Bo ṣe lu mi tan ni mo ko diẹ l'ara ẹru mi kuro ninu ile. Igba to ya ti oju ẹ wa silẹ lẹyin bi ọsẹ meloo kan lo pada wa bẹ mi pe ki n ma binu. Mo si jẹ ko yee pe mi o tun le pada sinu ile naa mọ, ayafi to ba gba ile sibomi in.
 
 
"O maa n pe mi pe ki n ba oun gbe omi wa sile, ti mo si maa n gbe e lọ fun un. Ko si ija kankan mọ l'aaarin wa, ṣugbọn nnkan t'emi atiẹ jọ n fa ni pe mi o le pada sinu ile yẹn mọ, ayafi ko lọ gba ile sibomi in.
 
 
"Ọmọ meji la ṣi bi, ibeji si l'awọn ọmọ naa. Ọdun 2018 la ko de inu ile naa, ṣugbọn ọdun to kọja ni wahala iya onile wa bẹrẹ, to je pe ko si nnkan ti a mọ ọn ṣe ninu ile to to tẹ ẹ l'ọrun."
 
 
Nnkan bi aago mejila kọja iṣẹju meji ni wọn sin Abayọmi si itẹku awọn onigbagbọ to wa l'adugbo Iṣabọ nilu Abẹokuta.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI