Pasitọ to fẹẹ gba aawẹ ogoji ọjọ bii ti Jesu ti gba ekuru jẹ lọwọ ẹbọra - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, February 17, 2023

Pasitọ to fẹẹ gba aawẹ ogoji ọjọ bii ti Jesu ti gba ekuru jẹ lọwọ ẹbọra


Pasitọ kan ti wọn lo fẹ gbiyanju lati gba aawẹ ati adura ologoji ọjọ ti Jesu Kristi gba lọjọsi ni iroyin ti fi to wa leti pe o ti gba ekuru jẹ lọwọ ẹbọra.
 
Francisco Barajah ni wọn pe Pasitọ, ọmọ orileede Mozambique ọhun.
 
Wọn ni ẹnu aawẹ naa lo wa, ti nnkan fi yiwọ mọ ọn lọwọ, to si gbabẹ sọda sọrun alakeji.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI