Asiri iku to pa Jide, omo Asiwaju Tinubu - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, November 1, 2017

Asiri iku to pa Jide, omo Asiwaju Tinubu

Titi di bi a ti n sakojopo iroyin, inu ibanuje nla ni Asiwaju egbe oselu All Progressives Congress, APC, eni to tun je Gomina ipinle Eko tele, Asiwaju Bola Ahmed Tinubu atawon ebi e wa bayii lori bi won se padanu omo won, Jide lojiji.

Tinubu, Oloogbe Jide ati Mama e
Gege bi iroyin to te AWIKONKO lowo lati odo alaga egbe oselu naa nipinle Eko, Otunba Henry Oladele Ajomale nirole oni, o so pe ibanuje nla niku naa fawon ebi Tinubu lasiko yii.

Jide Tinubu la gbo pe odun 1999 ni won pe sinu egbe amofin orileede yi, iyen Nigerian Bar, to si lo si fasiti Liverpool lorileeede England nibi to ti ni iwe eri Masters ninu eko ofin Maritime.

Bo tile je pe a ko tii le so pato nipa ohun to sokunfa ilu Jide Tinubu titi ta a fi sakojopo iroyin yi tan, sugbon a fi n da yin lo ju pe ekunrere iroyin naa n bo lai pe, e ku oju lona

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI