KOLA ABIOLA GBA AWOODU GCFR FUN BABA E, MKO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, June 12, 2018

KOLA ABIOLA GBA AWOODU GCFR FUN BABA E, MKOKolawole Abiola to je omo to dagba ju ninu awon omo oloogbe Oloye Moshood Kashimawo Olawale Abiola ti gba awoodu tawon aare orileede Naijiria ma n gba, iyen GCON (Grand Commander of the Federal Republic) fun baba e.

Nigba to n gba awoodu naa, Kolawole Abiola so pe inu oun dun fun Aare Muhammadu Buhari se ranti baba oun lasiko yi, eyi tawon Aare to ti koja lo ko se fun baba oun.

O loun mo pe Aare tooto ni Buhari, ti ko si nii soju saaju enikeni. Bee lo dupe lowo gbogbo awon to sagbateru eto awoodu naa ati bi won tun se yi ojo ayeye isejoba awarawa kuro ni ojo kokandinlogbon, osu karun si ojo kejila osu kefa odoodun.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI