OUNJE REPETE: AMBODE ATI FAYOSE TOWO B’OWE ADEHUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, June 29, 2018

OUNJE REPETE: AMBODE ATI FAYOSE TOWO B’OWE ADEHUN


Se ni idunnu subu lu ayo awon omo ipinle Eko ati Ekiti nigba ti won gbo pe Gomina Ayodele Fayose ati Gomina Akinwunmi Ambode ti joo towo b’owe adehun (MoU) lori ona ti won yoo gba lati maa gbin iresi (rice), eyi ti yoo mu ki ounje po jaburata fawon araalu lati maa ri je lasiko.

Titi di bi e ti n ka iroyin yi lawon omo ipinle mejeeji yi, iyen Eko ati Ekiti si fi n ki awon gomina won fun asoyepo naa.

Gege b’AWIKONKO se gbo, ori ero ayelujara ni Gomina Ayodele Fayose ti soro naa sita lojo Tosde to koja yip e igbadun ti de fawon omo ipinle mejeeji yii, ati pee to oro aje won yoo tubo gbe peeli sii.

Gomina Fayose so pea won ti setan lati pese awon ile (land) ti won yoo gbin awon iresi naa si, to si je pe ijoba ipinle Eko ni yoo pese awon eso iresi ati owo ti won fe e lo.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI