IDIBO ABELE APC: BAYII LAWON IPINLE YOO SE DIBO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, September 26, 2018

IDIBO ABELE APC: BAYII LAWON IPINLE YOO SE DIBO

Lati yanju wahala to see se ko waye legbe oselu APC leyin idibo abele sawon ipo ijoba lodun 2019, paapaa lati yan awon adije sipo gomina kaakiri ipinle lorileede Naijiria, egbe oselu APC lapapp ti bu owo lu bawon ipinle yoo se yan awon ti yoo dije nibi idibo odun 2019 to n bo.


Ojo Abameta Satide to n bo yi, iyen ojo kokandinlogbon ni idibo yoo waye ninu egbe oselu APC kaakiri orileede Naijiria, nibi ti won yoo ti yan awon ti yoo jade dupo naa, iyen candidates.

Bayii ni awon igbimo agba amuseya egbe oselu naa, iyen National Working Committee (NWC) se bu owo luuluu bi yoo se lo sii.

1. ABIA DIRECT - PRIMARIES
2. ADAMAWA - INDIRECT PRIMARIES
3. AKWA IBOM - DIRECT PRIMARIES
4. ANAMBRA - DIRECT PRIMARIES
5. BAUCHI - DIRECT PRIMARIES
6. BAYELSA - DIRECT PRIMARIES
7. BENUE - INDIRECT PRIMARIES
8. BORNO - INDIRECT PRIMARIES
9. CROSSRIVER - DIRECT PRIMARIES
10. DELTA - INDIRECT PRIMARIES
11. EBONYI - INDIRECT PRIMARIES
12. ENUGU - INDIRECT PRIMARIES
13. EDO - DIRECT PRIMARIES
14. EKITI - DIRECT PRIMARIES
15. GOMBE - INDIRECT PRIMARIES
16. IMO - DIRECT PRIMARIES
17. JIGAWA - INDIRECT PRIMARIES
18. KADUNA - INDIRECT PRIMARIES
19. KANO - DIRECT PRIMARIES
20. KASTINA - INDIRECT PRIMARIES
21. KEBBI - INDIRECT PRIMARIES
22. KOGI - INDIRECT PRIMARIES
23. KWARA - INDIRECT PRIMARIES
24. LAGOS - DIRECT PRIMARIES
25. NASARAWA - INDIRECT PRIMARIES
26. NIGER - DIRECT PRIMARIES
27. OGUN - DIRECT PRIMARIES
28. ONDO - DIRECT PRIMARIES
29. OSUN - DIRECT PRIMARIES
30. OYO - INDIRECT PRIMARIES
31. PLATEAU - INDIRECT PRIMARIES
32. RIVERS - INDIRECT PRIMARIES
33. SOKOTO - INDIRECT PRIMARIES
34. TARABA - DIRECT PRIMARIES
35. YOBE - INDIRECT PRIMARIES
36. ZAMFARA - DIRECT PRIMARIES
37. FCT - DIRECT PRIMARIESNo comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI