AMUSA FIPA BA IYAWO AYALEGBE WON SUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, October 28, 2018

AMUSA FIPA BA IYAWO AYALEGBE WON SUN

"Ise esu ni, mi o mon on mo" loro ebe to n tenu odomokunrin eni odun merinlelogun (24) nni, Amusa Adam jade lose to koja yi, nigba ti won fesun kan an pe o fipa ba iyawo okan lara awon ayalegbe baba e sun.


AWIKONKO gbo pe o ti pe ti Amusa ti n wa ona bi yoo se fipa ba obinrin naa sun latari bo se rewa pupo, sugbon lojo naa ni Olorun fun un se.

Tesan olopaa lo si wa bayii to n rawo ebe.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI