KAYEEFI NLA: OMODUN META P'OKUNSO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, November 11, 2018

KAYEEFI NLA: OMODUN META P'OKUNSO

Bo tile je pe awon to firoyin omodun meta kan ti won ni won ba loke aja ko fi ibi isele naa ti sele sowo si wa, sugbon kayeefi lọrọ naa sí n je fún ọpọ àwọn eeyan.


Ohun tá a gbo ni pe iya omo naa lo jade lọ jade lọ ra nnkan, igba ti yóò fi dé, omodun meta e yi ti sere gùn oke ile akoku ti won n gbe lati sere.

Ibi ti omo naa ti n sere kaakiri oke ile naa la gbo pe ẹsẹ é tí yẹ, to sì fẹ é ṣe bẹ jabo, sugbon ta a gbo pe irin kan to yo sonso ti fa a duro.

Fún bí ogun iseju lati gbo pe omo naa lo ko too dagbere faye. Igba ti iya omo naa dé lo ba omo e loke to ti kú, ariwo é lo kan s'awọn araadugbo, ti won sì gbé omo naa sokale.

Ohun tawon eeyan kọkọ ro pe ni é ṣe lomo naa lo pokunso fúnra è.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI