AWIKONKO gbo pe onii tii se Tosde lo ye ki eto akanse adura olojo meji ti won ti fe e sise iyanu owo, iyen Miracle Money waye, sugbon oru moju Monde ni obinrin naa dagbere faye.
Bawon kan se n so pe eto akanse adura ise iyanu owo naa kii soju lasan, nitori pe Olorun ko see se ki Olorun ro ojo owo kale lati orun.
Bee lawon kan n so pe Pasito naa ati oko e, Apositeli Joshua Drumgbe gbona pupo to ba di oro ise iyanu.
A gbo pe opo awon eeyan ni won ti n mura sile fun ipade adura, ta a ko sì tii le fidi e mule pe yoo waye mo.
Pasito Joshua la gbo pe o kede iku iyawo fawon eeyan.
No comments:
Post a Comment