LEYIN IKU FASEHUN, OMOBA OSHIBOTE DI ADARI EGBE OPC - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, December 2, 2018

LEYIN IKU FASEHUN, OMOBA OSHIBOTE DI ADARI EGBE OPC


Lesekese ti oludasile ẹgbẹ Oodua Peoples' Congress, OPC, Oloogbe Frederick Fasehun ti doloogbe, iyen lojo Satide ana lawon to tun je gege bi olori ninu egbe naa ti kede Omoba Oshibote Oodua gege bi adari won.

Gege b'AWIKONKO se gbo, inu gbongan ipade ti ile itura Century, eyi to wa lagbegbe Okota niluu Eko ni won ti sare sepade ranpe lati kedun oga won, nibe ni won tun ti lo anfààní naa lati fa Omoba Oodua kale gẹgẹ bí ẹni tí yoo tẹsiwaju iṣẹ ti Oloogbe naa fi silẹ ko too ku.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI