SUPER FALCONS TI YEGE NIBI IDIJE AWCON - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, December 1, 2018

SUPER FALCONS TI YEGE NIBI IDIJE AWCON

Segun Okeowo


Egbe agbaboolu Super Falcons ti orileede Naijiria, iyen awon obinrin ti yege nibi idije asekagba ti idije Women Africa Cup of Nations, AWCON todun 2018 to waye niluu Accra, lorileede Ghana.

Akẹgbẹ wọn, Bayana-Bayana ti orileede South Africa ni won f'eyin won gbole lale oni ojo kinni in osu kejila, leyin ti won gba oomi ayo, eyi to mu won gba penariti.


Bẹ o ba gbagbe, odun 2000 lawon ẹgbẹ agbaboolu mejeeji yi ti pade ara won gbeyin nipele asekagba, eyi ti ẹgbẹ agbaboolu Super Falcons f'eyin won gbole leyin aami ayo meji si odo.

Lale onii, aami ayo merin si meta ni Super Falcons bori i Bayana-Bayana.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI