O TAN; FẸMI KUTI LOUN KO FẸ DABI BABA OUN, FẸLA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 17, 2019

O TAN; FẸMI KUTI LOUN KO FẸ DABI BABA OUN, FẸLA

Ọkan lara awọn ọmọ gbajumọ olorin Afro to ti di oloogbe, Fẹla Anikulapo Kuti, toun naa tun ti wa a di agba-ọjẹ nidi iṣẹ orin Afrobeat, Fẹmi Kuti ti sọ pe ko wu oun lati tọ ipasẹ baba to bi oun lọmọ. dipo bẹẹ, oun yoo kuku tọ ipasẹ ara oun, koun si maa ṣe bi ara oun.

Ori ẹka ayelujara, iyẹn Twitter ni Fẹmi ti sọrọ naa lasiko to n fesi si ibeere ti ọkan lara awọn olofẹ ẹ beere lọwọ ẹ pe ki lo fa a toun ko fi maa kọrin tole bii ti baba ẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI