O TAN O: ATIKU ṢABEWO SI WASHINGTON DC - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 17, 2019

O TAN O: ATIKU ṢABEWO SI WASHINGTON DC


Lati nnkan bi aago mẹjọ kọja iṣẹju mẹtadinlọgbọn ti igbakeji Aarẹ tẹlẹri lorileede yi, Alaaji Atiku Abubakar ti kede sita lori ẹka ayelujara ti Twitter pe oun ti balẹ si ilu-ilu ilẹ Amẹrika tii ṣe Washington DC lawọn olofẹ ẹ ti bẹrẹ sii fi awọn ọta okunrin naa ṣẹlẹya pe oju ti wọn, ọga awọn pada de ibi tawọn eeyan ko lero pe o le lọ.

Image result for atiku arrives us
Gẹgẹ bi iroyin yi to tẹ AWIKONKO lọwọ ṣe sọ, Atiku ati Sẹnetọ Bukọla Saraki to je Aarẹ ile igbimọ aṣofin agba lorileede yi lo tẹle e lọ gbatẹgun nibẹ.


Image result for atiku arrives us

A gbọ pe ipade alaafia ni Atiku lọ ọ ṣe pẹlu awọn alaṣẹ orileede US, ta a si gbọ pe ko ṣẹyin Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ

Gbara to de'bẹ la gbọ pe wọn ti tẹwọ gba a.










Just arrived Washington D.C for meeting with US government officials, Nigerians living in D.C metropolis and the business community. -AA


fffff

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI