ỌRỌ BURUKU TOUN TẸRIN: OṢIṢẸ IBEDC TO LỌỌ JA INA WỌ GAU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, May 27, 2019

ỌRỌ BURUKU TOUN TẸRIN: OṢIṢẸ IBEDC TO LỌỌ JA INA WỌ GAU

Bo tilẹ jẹ pe a ko tii mọ ibi tiṣẹlẹ naa ti ṣẹlẹ dasiko ta a kọ iroyin yi tan, ṣugbọn awọn fọto ti wọn fi ranṣẹ si wa jẹ ko ye wa pe pẹlu ibinu ni baale ile kan fi doju ija kọ ọkan lara awọn oṣiṣẹ mọnamọna to fẹ lọ ọ ja ina ile ẹ.

 
Opin ọsẹ to kọja yi niroyin naa tẹ AWIKONKO lọwọ, pẹlu awọn fọto ibi ti wọn ti n fa wahala naa.
 
A gbọ pe o ti pẹ ti ina ko ti si ladugbo naa, ṣugbọn ti wọn jaja fun wọn. Ina naa ko tii to wakati mẹta ti wọn fun wọn, ni wọn lawọn oṣiṣẹ mọna-mọna debẹ lati gba owo ina, to si jẹ pe ija ni wọn fi pade wọn.
 
\ 
 
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI