AWỌN EEYAN SỌRỌ LORI FỌTO TỌKỌ-TIYAWO OJU ỌNA YII - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, June 23, 2019

AWỌN EEYAN SỌRỌ LORI FỌTO TỌKỌ-TIYAWO OJU ỌNA YII

Pupọ ninu awọn to ri awọn fọto tọkọ-tiyawo oju ọna yi ni wọn n woye pe bawo ni wọn ṣe fẹẹ maa gbe latari bi wọn ṣe sanra-rọbọtọ.

plus-sized couple 
Bawọn eeyan ṣe n sọ oriṣiriṣi la rii pe awọn tọkọ-tiyawo ti wọn palẹmọ igbeyawo wọn ko ti ẹ rii ro rara, di po bẹẹ ṣe nifẹ wọn tun ga sii.

plus-sized couple


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI