ṢANAWỌLE, OGBOLOGBO ỌMỌDUN MỌKANLA TO N Ṣ'ẸGBẸ OKUNKUN L'EKOO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, June 9, 2019

ṢANAWỌLE, OGBOLOGBO ỌMỌDUN MỌKANLA TO N Ṣ'ẸGBẸ OKUNKUN L'EKOO

 

Ọdun 2017 ni fọnran kan gba ori ayelujara kan, nipa ọmọdekunrin ọmọdun mọkanla kan to jẹ ogbologbo ọmọ ẹgbẹ okunkun.

O ṣee ṣe ki ẹ ma ranti mọ, idi ni yi ti a fi wo o pe ka muu pada si iranti yin.

Diẹ lara awọn fọtọ ọmọ naa re nigba to pade igbala
 

 

 

 

 

 

Ẹ wo fidio naa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI