AWỌN EEYAN N SỌRỌ LORI FỌTO ALUPAYIDA FUNKẸ AKINDELE NIHOHO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, July 26, 2019

AWỌN EEYAN N SỌRỌ LORI FỌTO ALUPAYIDA FUNKẸ AKINDELE NIHOHO

Ọpọ awọn to ri fọto gbajugbaja oṣere oloyinbo nni, Genevieve Nnaji nibi to bo ara silẹ nihoho lori ayelujara ni wọn ko fẹẹ le pa ẹnu wọn de, tawọn eeyan si sọ oriṣiriṣi nipa fọto naa.

Ko pẹ ti fọto naa jade sita ni Funkẹ Akidele-Bello, iya Ibeji naa gbe fọto ti ẹ, to ti ṣe alupayida ti Genevieve sita, to si sọ pe ibeji lawọn, kẹnikẹni ma ṣe sọ ohunkohun lee lori.

Fọto naa lẹ n wo yii. Ki lẹyin naa fẹẹ sọ?

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI