WỌN FI OYE TUNTUN DA JONATHAN L'ỌLA NILẸ IBO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Monday, July 1, 2019

WỌN FI OYE TUNTUN DA JONATHAN L'ỌLA NILẸ IBO

Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, Aarẹ ana lorilẹ-ede Naijiria, Goodluck Ebele Jonathan ti gba oye tuntun nilẹ Ibo, iyẹn niluu Onitsha.

 
Bẹ o ba gbagbe, lọsẹ to kọja ni Goodluck Johnathan ṣabẹwọ lọọ si Aafin Obi tiluu Onitsha, nibẹ ni wọn ti fi oye tuntun da a lọla gẹgẹ bi ọkan lara awọn to n gbe ilẹ Ibo larugẹ kaakiri agbaye.

 
Diẹ lara awọn fọto ibi ti wọn ti da a lọla niwọn yii.
 


No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI