IPELE KEJI AWỌN TO LỌ MẸKA NIPINLẸ OGUN TI DE SAUDI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉFriday, August 2, 2019

IPELE KEJI AWỌN TO LỌ MẸKA NIPINLẸ OGUN TI DE SAUDI

Bi ẹ ṣe n ka iroyin yi, ipele keji awọn to lọ si irin ajo Hajj niluu Mẹka (Mecca) lorilẹede Saudi Arabia ti balẹ bayii, ti wọn si ti bẹrẹ abẹwo kaakiri bayii.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, awọn 174 la gbọ pe wọn gbera lati ipinlẹ Ogun, to si jẹ pe aarọ ana tii ṣe Tọside ni wọn balẹ sibẹ.

Al Ilyas centres to wa ni Mẹdina,  Saudi Arabia la gbọ pe wọn de si, nibẹ ni wọn si ti bẹrẹ abẹwo siyaroh kaakiri.

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI