PAUL, ỌMỌDUN MẸRINDINLOGUN TO YEGE JU NINU IDANWO WAEC RE O - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉFriday, August 2, 2019

PAUL, ỌMỌDUN MẸRINDINLOGUN TO YEGE JU NINU IDANWO WAEC RE O

Titi dasiko ti a kọ iroyin yi tan lọrọ ọdọmọkunrin kan ti wọn pe orukọ rẹ ni Kondu Paul Sopriye ti wọn loun lo yege ju nini idanwo aṣekagba tile ẹkọ girama to kọja yi, iyẹn WAEC ṣi n ya lẹnu.

 
A1 la gbọ pe o mu delẹ ninu idanwo naa, to si tun gba maaki 330 ninu idanwo JAMB to tun ṣe.
 

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI