AARẸ BUHARI GBA GBOGBO AWỌN ABẸNUGỌN ILE IGBIMỌ AṢOFIN NAIJIRIA LALEJO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉFriday, November 22, 2019

AARẸ BUHARI GBA GBOGBO AWỌN ABẸNUGỌN ILE IGBIMỌ AṢOFIN NAIJIRIA LALEJO

L'Ọjọbọ Tọside ana ni Aarẹ orilẹ-ede Naijiria, Ọgagun Muhammadu Buhari gba gbogbo awọn abẹnugọn ile igbimọ aṣofin kaakiri orilẹ-ede yi lalejo nile agbara to wa niluu Abuja.No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI