FỌTO: AWỌN AKẸKỌỌ ṢAYẸYẸ ỌSẸ IMỌ-ẸRỌ 'TẸKINỌLỌJI' NIPINLẸ ONDO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, November 22, 2019

FỌTO: AWỌN AKẸKỌỌ ṢAYẸYẸ ỌSẸ IMỌ-ẸRỌ 'TẸKINỌLỌJI' NIPINLẸ ONDO

Gbogbo awọn akẹkọọ patapata nipinlẹ Ondo ti wọn kopa nibi eto ayẹyẹ imọ-ẹrọ tọdun 2019 ni wọn ko le tete gbagbe ọjọ naa pẹluu oriṣiriṣi ẹkọ ti wọn ri kọ nibẹ.

Eto tọdun yi ti wọn pe akori ẹ ni "Our World of Science; Hope for Industrialization in Ondo State" lo waye ninu gbagede Community Education Resource Centre to wa ni Ayedun Quarters niluu Akurẹ.

Diẹ re lara awọn fọto bi eto naa ṣe lọ.







No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI