ỌNỌREBU ALEX AKINYẸMI GBA AAMI ẸYẸ GẸGẸ BI ALAGA IJỌBA IBILẸ TO PEREGEDE JULỌ L'ABUJA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, November 22, 2019

ỌNỌREBU ALEX AKINYẸMI GBA AAMI ẸYẸ GẸGẸ BI ALAGA IJỌBA IBILẸ TO PEREGEDE JULỌ L'ABUJA

Alaga ijọba ibilẹ Ifẹdọrẹ nipinlẹ Ondo, Ọnọrebu Alẹx Akinyẹmi ti gba aami ẹyẹ gẹgẹ bi ọkan laraawọn alaga ijọba ibilẹ ti wọn n ṣiṣẹ takun-takun kaakiri awọn agbegbe wọn.

Ọnọrebu Akinyẹmi to tun jẹ alaga gbogbo awọn alaga ijọba ibilẹ lorilẹ-ede Naijiria la gbọ pe wọn tun da lọla fun ti imọ ati ọgbọn to ni gẹgẹ bi adari rere.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI