EYI L’AWỌN AṢIRI TO TUN TU L’ẸYIN IKU ỌKỌ OLOYUN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉWednesday, January 29, 2020

EYI L’AWỌN AṢIRI TO TUN TU L’ẸYIN IKU ỌKỌ OLOYUN

Bo til jẹ pe, awọn Ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ ti l'awọn wa l’ẹnu iwadii iku gbajumọ oniṣegun ibilẹ nni, Alaaji Abdul-Fatai Yusuf ti gbọgbọ aye mọ si ỌKỌ OLOYUN, ṣugbọn ti wọn ko tii fi abajade iwadii naa s'ita d'asiko ta a ṣ’akojọpọ iroyin yii tan.

o ranti pe, gbara ti wọn pa Ọkọ Oloyun, awọn Ọlọpaa ni awọn ti n f’ọrọ wa awọn Ọlọpaa meji to t le e at’awọn oṣiṣẹ rẹ kan l’ẹnu wo, ṣugbọn ta a gbọ pe, awọn Ọlọpaa ri aṣiri nla kan gbọ pe, o ṣee ṣe k'awọn oṣiṣẹ ab Ọkọ Oloyun kan at’awọn to sun mọ ọn pupọ mọ nipa iku rẹ.

ga Ọlọpaa kan n'ipinlẹ Ọyọ to ni ka mae daruk oun ni, airi iwe jibiti t'awọn oṣiṣẹ Ọkọ Oloyun ṣe lo tu si kunrin naa l'w, ti wọn si sare dana sun awọn iwe naa. O ni, o ṣee ṣe ko jẹ pe wọn mọ nipa iku alaaanu ọpọ eeyan naa lati bo aṣiri wọn to tu si i l’ọwọ.

O jẹ ko ye wa pe, eto s'ogun-d'ogoji ti Ọkọ Oloyun n ṣe, iyn Option C ti awọn eeyan ti n f'owo da oko-owo n'ileeṣẹ Ọkọ Oloyun, ti wọn yoo si fun wọn ni idamwaa owo naa l'yin asiko perete tun wa l'ara awọn nnkan t'awọn fura si, koda to ni aksil awọn ni tean Ọlọpaa agbegbe Igando to wa l'Ekoo n'itosi ileeṣẹ Ọkọ Oloyun fihan pe, ọpọ eeyan lo ti gbe ẹjọ Ọkọ Oloyun lo sibẹ nitori wọn ko tete r'owo wọn gba.

Gbogbọ eyi ni Ọga Ọlọpaa naa ni iwadii awọn de duro lati mọ ibi ti iku gbajumọ oniṣegun ibilẹ naa ti wa. a o, aṣiri nla tu si wa l’ọwọ pe, ou kejila dun to kja ni Ọkọ Oloyun gba awọn ayewe-owo-wo (auditor) lati ewadii bi owo ṣe n wle ati bo ṣe n jade n'ileeṣẹ rẹ, paapaa n'igba ti gbese awọn onibaara Option C p l'run rẹ.

Nib laa gbọ pe, aṣiri obitibiti owo t'awọn oṣiṣẹ Ọkọ Oloyun kan ṣe baṣu-baṣu ti tu si i l’ọwọ. L'j t'iṣẹl iku rẹ naa ṣẹlẹ, otẹẹli ni Ọkọ Oloyun wa n'ipinlẹ Ogun t'iyawo rẹ fi pe e pe, awọn kan dana sun awọn iwe pataki kan ni fiisi rẹ.

L'yin wakati di si asiko naa ni Ọkọ Oloyun gba ipinlẹ Ọyọ l, ki wọn too pa a si oju ọna Igbo-Ora. Awọn ara agbegbe t'iṣẹlẹ naa ti sele ti wọn s'oro ni, iṣẹlẹ naa s'oju awọn. kunrin ọlọkada kan ni agbegbe naa to n jẹ Dauda jediran ni, agbegbe Akeroro l'oju na Eruwa si Igbo-ra n'ipinlẹ Ọyọ ni wọn pa Ọkọ Oloyun si.

O ni, aṣọ dudu l'awọn to pa kunrin naa w, ati pe Ọkọ Oloyun nikan ni wọn klu ninu awọn ti wọn j kwọọ rin. O jẹ ko di mimọ pe, aarin ibudo awọn Ọlọpaa oriṣiiriṣii meji ọtọọtọ ni wọn pa Ọkọ Oloyun si. O fi kun un pe, bo tilẹ jẹ pe iṣẹlẹ ijinigbe p l'oju na hun daadaa, ṣugbọn ti ko si ipaniyan iru ti Ọkọ Oloyun bẹẹ.

kunrin to n fi kada rẹ na na hun daadaa wa be ijọba pe, awọn fijilante lo le ṣẹgun wahala ọna naa. O ni, owo l'awọn Ọlọpaa oju ọna ohun maa n gba l’ọwọ awọn t'awọn jẹ ọlọkada, to si ni ọpọ igba t'awọn Ọlọpaa ba ri awọn ajinigbe ati oniṣẹ ibi ni wọn maa n b aṣọ ọlọpaa l'orun, ti wọn yoo salọ, koda to ni wọn yoo ni awọn naa l'ọmọ n'ile, ṣugbọn to l'awọn fijilante ni ki i bẹru, ti wọn maa n k'oju awọn oniṣẹ ibi.

Araalu mi-in to tun s'ọrọ ni, awọn to pa Ọkọ Oloyun ti n t le e tip, ti wọn si n ṣọ titi ti wọn fi f'ibn pa a nipakupa. Tiṣa, iyẹn oluk to k Ọkọ Oloyun n'ileewe Muslim High School to wa l'agbegbe Iktun n'ipinlẹ Eko, iyẹn Alagba Adeyẹmi Okeronbi t'oun naa n gbe agbegbe ti wọn pa Ọkọ Oloyun si ni, awọn agbanipa lo pa a.

O ni, gẹgẹ bii Ọga ẹgbẹ OPC t'oun jẹ tẹlẹ ati b'oun ṣe jẹ balogun ẹgbẹ awọn oniṣegun ibilẹ niluu Igbo-ra, o da oun l'oju pe, awọn ẹṣọ aabo ibilẹ lo le yanju eto aabo agbegbe hun nitori to ni b'awọn Ọlọpaa ba gbọ ariwo taya mto to b lasan, nie ni wọn maa n salọ, ṣugbọn to l'awọn fijilante ki i bẹru.

O fi kun un pe, idagbasoke agbegbe awọn ni Ọkọ Oloyun wa fun lati da ileeṣẹ sil, ṣugbọn to ni wọn pa a nipakupa.

a o, ọrẹ Ọkọ Oloyun kan to s'r ni, ọrọ owo nla kan pa Ọkọ Oloyun at'awọn kan p, to si lo ṣee ṣe ko jẹ awọn eeyan naa lo ran awọn agbanipa si i, ṣugbọn to ni awọn di ni aṣiri ọrọ owo naa han si.

Ọkọ Oloyun funra rẹ ko ai fura pe, awọn kan n lepa mi rẹ ko too ku. Lati ọjọ Aje, iyẹn Mnde ọsẹ to l yii titi d'jru, iyẹn Wsidee to ku ọjọ kan oo ti yoo ku ni Ọkọ Oloyun ti n k awọn ọrọ ifura si ori ẹrọ ayelujara Fesibuuku (Facebook) rẹ.

Nie ni gbajumọ oniṣegun ibilẹ naa n s pe, ki lrun gba oun l’ọwọ awọn to sunm oun bii ian run, ti wọn n ba oun jẹ, ba oun mu, ṣugbọn ti wọn n lepa oun kiri.

L'akootan, j Abamta, iyẹn Satide s yii ni adura Fidau yoo w'aye fun un n'ile igbaf Ọkọ Oloyun Fun City to wa ni Hotel bus stop ni Igando, ipinlẹ Eko nibi t'awọn eeyan yoo ti pejọ lati edaro ati lati gbadura fun akni nla to l.

Awọn fto ti tun n wo yii ni awọn ileeṣẹ Ọkọ Oloyun to wa ni titipa ni ana yii at'awọn eeyan to f'owo d'oko-owo Option C l'd rẹ ti wọn ya l s'ileeṣẹ rẹ l's to kja lati beere owo wọn. Bi gbọgbọ nnkan ba ṣe n l ni o maa gbọ ni ikanni yii

No comments:

Post a CommentPÍN-IN KÁÀKIRI