ỌMỌ SỌJI AMOSU, ALAGA ẸGBẸ AKỌROYIN N'IPINLẸ OGUN K'ẸKỌỌ GB'OYE NI FASITI ILỌRIN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, January 24, 2020

ỌMỌ SỌJI AMOSU, ALAGA ẸGBẸ AKỌROYIN N'IPINLẸ OGUN K'ẸKỌỌ GB'OYE NI FASITI ILỌRIN

BỌSUN ỌLANIYI, ABẸOKUTA - Ṣẹnkẹn bayii ni idile Kọmureedi Olusọji Amosu to jẹ alaga ẹgbẹ akọroyin n'ipinlẹ Ogun n dun n'igba ti ẹgbẹ awọn oniṣegun lorilẹ-ede Naijiria, iyẹn Medical and Dental Council of Nigeria fi oye Oniṣegun da ọmọ rẹ, Pius Ọpẹyẹmi Amosu l'ọla.

Eto ayẹyẹ naa la gbọ pe o waye n'ile-ẹkọ fasiti t'iluu Ilọrin, yẹn University of Ilorin l'Ọjọbọ Tọside ana.






No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI