ILU ṢAGAMU PA LỌLỌ BI WỌN ṢE SINKU YINKA MAFẸ, GBAJUMỌ ỌNỌREBU TO KU L'ỌJỌ IBI Ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, March 13, 2020

ILU ṢAGAMU PA LỌLỌ BI WỌN ṢE SINKU YINKA MAFẸ, GBAJUMỌ ỌNỌREBU TO KU L'ỌJỌ IBI Ẹ

Ṣe ni gbogbo ilu Ṣasgamu n'ipinlẹ Ogun pa lọlọ lonii, nigba ti wọn ṣe eto isinku gbajumọ Ọnọrebu to ku laipẹ yii, iyẹn Ọnọrebu Yinka Mafẹ to jẹ olori ọmọ ile igbimọ aṣofin to pọ ju ninu ijọba to kọja yii.

Image may contain: 5 people, people standing
Lara awọn to wa nibi eto isinku naa ni Sẹnetọ Ibikunle Amosun, Yetunde Ọnanuga to jẹ igbakeji gomina ana n'ipinlẹ Ogun, Amofin Taiwo Adeoluwa to jẹ akọwe ijọba Amosun, Ọnọbe AbdulKabir Akinlade at'awọn mi-in.

Image may contain: 3 people, people sitting and indoor
Ẹṣe ko gbero rara, ko da, ṣe ni omije n pe omije ran niṣẹ, ki Ọlọrun ba wa tẹ oloogbe naa si afẹfẹ rere.Image may contain: 1 person, outdoor

Image may contain: 1 person

Image may contain: one or more people


Image may contain: one or more peopleNo comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI