Ẹ WÒ BÍ IBÙDÓ AYẸWO FÚN ÀRÙN KORONAFAIRỌỌSI T'IJỌBA KWARA KỌ SI ṢOBI ṢE RI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, April 21, 2020

Ẹ WÒ BÍ IBÙDÓ AYẸWO FÚN ÀRÙN KORONAFAIRỌỌSI T'IJỌBA KWARA KỌ SI ṢOBI ṢE RI


Bẹẹdi tí kò din ni ọgọ́ta lo gba ọsibitu ayasọtọ fún ibùdó ayẹwo àrùn aṣekupani tí COVID-19, èyí tí ìjọba ìbílẹ̀ Kwara ṣe lẹ ń wo yìí.

Ọ̀pọ̀ àwọn tó ń rí í ní wọn ń ṣe sadankata fún Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lórí bo ṣé gbé ọsibitu náà kalẹ tó sì bá ọ́nà ìgbàlódé mú.

Ọsibitu náà, ìyẹn Sobi Specialist Hospital lẹ ń wo yìí, nibẹ náà ni wọn ti ń tọju àwọn tó ní àrùn COVID-19.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI