KORONAFAIRỌỌSI! ILEEṢẸ BUA FÚN ÌPÍNLẸ̀ KWARA NÍ ỌGỌ́RÙN-ÚN MILIỌNU NÁÍRÀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, April 30, 2020

KORONAFAIRỌỌSI! ILEEṢẸ BUA FÚN ÌPÍNLẸ̀ KWARA NÍ ỌGỌ́RÙN-ÚN MILIỌNU NÁÍRÀ


Ko dín ni miliọnu lọ́nà igba-le-lọgbọn {N230} náírà lowo t'ijọba ipinlẹ Kwara tí rí gbà lọ́wọ́ àwọn ẹlẹyinju àánú káàkiri ipinlẹ náà, pàápàá káàkiri àgbáyé.

Lónìí ní ileeṣẹ BUA, ìyẹn BUA Group tún fún ìjọba ipinlẹ náà ni ọgọ́rùn-ún miliọnu {N100,000,000} náírà fún gẹ́gẹ́ bí owó iranwọ ìpolongo lòdì sí aarun aṣẹkupani, Covid-19. 

Aláṣẹ àti oludasilẹ ileeṣẹ náà, Abdulsamad Rabiu lo ṣáájú eto naa gẹ́gẹ́ bí atẹjade tí akọwe Gómìnà, Rafiu Ajakaye fi síta. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI